terça-feira, 19 de fevereiro de 2008

Saudação antes da Primeira caída

IFA O GBỌ
ỌMỌ ẸNÍRẸ
ỌMỌ ẸNÍRẸ
ỌMỌ EJÒ MÉJI
TÍ Í SARE GANRANGANRAN LÓRÍ ERÉWÉ
AKÉRÉ F’INÚ ṢỌGBỌN
AKỌNILỌRÀN BI IYEKAN ẸNI
ÌBÀ AKỌDÁ
ÌBÀ AṢẸDÁ
ỌLỌJỌ ÒNÍ ÌBÀ A RẸ O
ASE ASE ASE

Nenhum comentário: