terça-feira, 19 de fevereiro de 2008

IJUBA IFA

OLỌJO ONI MOJÚBÀ RÉ
OLÙDAIYE MOJÚBÀ RÉ
MOJÚBÀ ỌMỌDE
MOJÚBÀ ÀGBÀ
BI ÉKÒLÓ BA JÚBÀ ILÈ
ILÈ A LANU
KI IBÀ MI SE
MOJÚBÀ AWỌN ÀGBÀ MẸRÌNDINLÓGUN
MOJÚBÀ BABA MI
MOJÚBÀ ỌRÚNMILA OGBAIYE GBỌRUN
OHUN TI MO BA WI LỌJỌ ONI
KO RI BÉÉ FUN MI
JỌWỌ MÁ JẸ KI ÒNÀ MI DI
NOTORI ÒNÀ KÌÍ DI MỌ ỌJÓ
ÒNÀ KÌÍ DI MỌ ÒGUN
OHUN TI A BA TI WI FUN ÒGBÀ L’ÒGBÀ NGBÀ
TI ÌLÁKỌSE MI ṢẸ LÁWUJỌ ÌGBÍN
TI EKESE NI NSE LAWOJO ÒWÚ
ỌLỌJỌ ÒNI KO GBA ỌRỌ MI YẸWÒ
YẸWÒ
AṢE AṢE AṢE

Nenhum comentário: