terça-feira, 19 de fevereiro de 2008

ORIKI OGUN

OGUN LAKAIYE
ỌSIN IMỌLẸ
OGUN ALADA MÉJÌ
OFI OKAN SANKO
OFI OKAN YENA
ỌJỌ OGUN NTI ORI OKE BỌ
AṢỌ INA LỌ MU BORA
ẸW ẸJẸ LOWO OGUN
ONILE OWO
ỌLỌ NA ỌLA
OGUN ONILE
KONGUN KONGUN
ỌRUN
OPỌN OMI SI ILE
FI ẸJẸ WUẸ
OGUN AWỌN LE INJU
EGBE LEHIN ỌMỌ KAN
OGUN MÈJÈ LOGUN MI

ORIKI ÈṢÙ

ÈṢÙ ỌTA ÒRÌṢÀ
ỌṢẸTURA LORUKỌ BABA MỌỌ
ALAGOGO IJA LORUKOIYA NPEE
ÈṢÙ ODARA ỌMỌ KUNRIN IDOLOFIN
OLE ṢONṢON SORI ẸSẸ ẸLẸSẸ
KOJẸ KOSI JẸKI ẸNI NJẸ GBE MI
AKI I LOWO LAI MUTI ÈṢÙ KU RO
AKI I LAIỌ LAI MUTI ÈṢÙ KU RO
AṢỌ TUN ṢOSI LAI NI ITIJU
ÈṢÙ APATA SỌMỌ ỌLỌMỌ LẸ NU
AFI OKUTA DI PO YIỌ
ALAGẸMỌ ORUN A NLA KA LU
PA PA WARA A TU KA MA ṢE ṢA
ÈṢÙ MA ṢE MI OMO ELOMIRA
NI KO ṢE

Saudação antes da Primeira caída

IFA O GBỌ
ỌMỌ ẸNÍRẸ
ỌMỌ ẸNÍRẸ
ỌMỌ EJÒ MÉJI
TÍ Í SARE GANRANGANRAN LÓRÍ ERÉWÉ
AKÉRÉ F’INÚ ṢỌGBỌN
AKỌNILỌRÀN BI IYEKAN ẸNI
ÌBÀ AKỌDÁ
ÌBÀ AṢẸDÁ
ỌLỌJỌ ÒNÍ ÌBÀ A RẸ O
ASE ASE ASE

IJUBA IFA

OLỌJO ONI MOJÚBÀ RÉ
OLÙDAIYE MOJÚBÀ RÉ
MOJÚBÀ ỌMỌDE
MOJÚBÀ ÀGBÀ
BI ÉKÒLÓ BA JÚBÀ ILÈ
ILÈ A LANU
KI IBÀ MI SE
MOJÚBÀ AWỌN ÀGBÀ MẸRÌNDINLÓGUN
MOJÚBÀ BABA MI
MOJÚBÀ ỌRÚNMILA OGBAIYE GBỌRUN
OHUN TI MO BA WI LỌJỌ ONI
KO RI BÉÉ FUN MI
JỌWỌ MÁ JẸ KI ÒNÀ MI DI
NOTORI ÒNÀ KÌÍ DI MỌ ỌJÓ
ÒNÀ KÌÍ DI MỌ ÒGUN
OHUN TI A BA TI WI FUN ÒGBÀ L’ÒGBÀ NGBÀ
TI ÌLÁKỌSE MI ṢẸ LÁWUJỌ ÌGBÍN
TI EKESE NI NSE LAWOJO ÒWÚ
ỌLỌJỌ ÒNI KO GBA ỌRỌ MI YẸWÒ
YẸWÒ
AṢE AṢE AṢE

Ogun

BI OMODÉ BÁ DA ILÈ, KÍ O MÁ SE DA ÒGÚN.
(UMA PESSOA PODE TRAÍR TUDO NA TERRA, SÓ NÃO DEVE TRAIR ÒGÚN).


A ko yènà, Òrísà bi Ògún oníìré kò sí mó Bí kò sí Ògún A ko roko Ògún lo no okó Ògún làgbède Ògún làgbè, oun naa ni jagún jagún Bi o si Ògún a ko jeun
Não existirá mais de uma divindade como Ògún Sem Ògún Não se limpa o mato (para plantar) Sem Ògún não se abre o caminho A enxada pertence a Ògún Ògún é ferreiro Ògún é agricultor e guerreiro Sem Ògún não há comida

domingo, 17 de fevereiro de 2008